Eyi ni eto iyinrere fun o gbogbo Agbaye
Idi ti a fin se Ajodun Ajinde.
Ekaabo si abala eto yii ti iyinrere fun o gbogbo Agbaye. Ninu abala eleyii pelu opolopo ibere ati iwe mimo bibeli, a fe je ki e le ronu. Ki ni koko idi gan oun ti a n se ni ori ero asoro ma gbesi yii? A wi
Jn.3:16 ti a ri ninu Bibeli so wipe - Tori Olorun fe araye to be ge ti O fi omo re kan soso fun n, pe enikeni ti o ba gbagbo ki yi o segbe sugbon yi o ni iye ainipekun
Bawo ni Olorun se le je mimo ati pipe ti o si fe gbogbo wa ni kan kan?
Koda ninu Ex 15: 13 - Ninu ife otito yin ni e ti dari awon eniyan yin yi e rapada. Ninu agbara yin ni e ti to won si ona ile mimon yin.
Ninu 2 korinti 13:14 Ki ore off Oluwa Jesu Kristi, ati ife Olorun, ati idapo ti emi mimo ki o wa pelu gbogbo yin.
Eyi ni ebun ore ofe nipase Jesu Kristi fun eni kan kan
Enikeni ti o ba gbagbo ki yi o segbe, sugbon yi o ni iye ainipekun.
Ti awon ti o gbagbo ba ni iye ainipekun, ki ni yi o a sele si awon ti ko gba ati igbawo?
Lk 12:46 - Oga omose naa yi o si wa ni ojo ti ko ro tele ti ko reti re ati akoko ti ko mon. Yi o si ge si wewe, o si fun ni ipin tire no odo awon aligbagbo.
Ki ni o n sele ni odo awon alaigbagbo?
Mt. 25:41 - "Nigbana, yi o si wi fun awon ti o wa ni apa osi re wipe, " kuro ni odo mi, o ti segbe, sinu ina ayeraye ti a pese fun esu ati awon angeli re
Se eyi le je onto?
Jn 14:17 - Emi otito.
Aye ko le gba nitoriti won ko ri tabi mon. Amon iwo mon nitori o n gbe pelu re, o si wa ninu re.
Eyi ni koko odun Ajinde lati fun wa ni ireti ati iye ainipekun. Lati je ki o se se nipase Jesu Kristi omo Olorun ki a le sa fun idakeji re.
A gbagbo ninu nkan ti Bibeli so fun wa. A gbagbo pe Jesu Krist omo Olorun ni Oluwa ati Olugbala. A gbagbo pe Jesu so fun awon omo leyin re lati lo sinu aye lati mun omo leyin to po si wa fun Jesu, Eyi ni a fi n se nkan ti a n se
Comments (0)
To leave or reply to comments, please download free Podbean or
No Comments
To leave or reply to comments,
please download free Podbean App.